Full width home advertisement

Travel the world

Climb the mountains

Post Page Advertisement [Top]

Akori: Itusile Kuro ninu ogun ifaseyin
Ese Oro Olorun: Eksodu 1:8-14
Kosi awawi pe ogun ifaseyin nyo opolopo eniyan lenu loni. Opo to nmura fun odun keresimesi lowo lowa labe igbekun ogun ifaseyin.
Oba Herodu Ati orileede re gbogun ti awon Omo Olorun, tiwon si fi won sinu ide yi fun opo odun. O sese ki iwo pelu wa ninu Igbekum ifaseyin. Boya ise re kolo dede, tabi ile iwe ti di eti fun o. Osese ki igbeyawo re ma mu eso Omo jade lati ojo ti iwo pelu Ayanfe ti gbe ra yin Sile gegebi Oko ati aya. Bi oti nko owo jo fun ilekiko tabi fun moto rira ni gbobgbo re ntuka. Mo fi daoloju pe oni ni opin de ba ogun ifaseyin ninu aye re.
Ara Adura:
1. Ni oruko Jesu, gbogbo ogun ifaseyin ninu aye MI, ina ajonirun Olorun jo yin run.
2. Gbogbo ipile ogun ifaseyin ninu aye MI, ni oruko Jesu e ma gbina.
3. Ni oruko Jesu, moja Gbogbo ide ifaseyin tafi de aye ati ise mi mole.
4. Gbogbo irugbin ifaseyin ninu aye MI, mofa yin tu loruko Jesu.
5. Gbogbo iserere ti ogun ifaseyin ti gba lowo MI, mogba pada loni loruko Jesu.
6. Baba mi ati Olorun MI, agbara itesiwaju ninu ohun rere Gbogbo mo gba ni oruko Jesu

No comments:

Post a Comment

Bottom Ad [Post Page]