Full width home advertisement

Travel the world

Climb the mountains

Post Page Advertisement [Top]

Adura fun Anu Olorun se pataki o se koko fun Omo Olorun. Adura anu je adura to ma nsilekun fun ire lona
gbogbo. O ma nmu ki eniyan ri anu gba lodo gbogbo eniyan.

Adura anu kise adura serese, o je adura ti eniyan ma ngba tokantokan pelu okan igbagbo tooto.

No comments:

Post a Comment

Bottom Ad [Post Page]